Mátíù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì pe ọmọ kékeré kan sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀. Ó sì mú un dúró láàrin wọn.

Mátíù 18

Mátíù 18:1-3