Mátíù 18:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo tún sọ èyí fún yín, bí ẹ̀yin méjì bá fi ohùn ṣọ̀kan ní ayé yìí, nípa ohunkóhun tí ẹ béèrè, Baba mi ti ń bẹ ní ọ̀run yóò sì ṣe é fún yín.

Mátíù 18

Mátíù 18:9-26