Mátíù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Pétérù ti sọ̀rọ̀ tán, àwọ̀sánmọ̀ dídán síji bò wọ́n, láti inú rẹ̀ ohùn kan wí pé, “Èyí ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹni ti inú mi dùn sí gidigidi. Ẹ máa gbọ́ tirẹ̀!”

Mátíù 17

Mátíù 17:1-13