Mátíù 17:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì dé ọ̀dọ̀ ìjọ ènìyàn,. ọkùnrin kan tọ̀ Jésù wá, ó sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀, ó wí pé,

Mátíù 17

Mátíù 17:6-18