Mátíù 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì dáhùn pé, “Dájúdájú òtítọ́ ni wọ́n ń sọ. Èlíjà wá láti fi gbogbo nǹkan sí ipò.

Mátíù 17

Mátíù 17:5-17