Mátíù 16:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì kìlọ̀ fún wọn pé, “Ẹ kíyè sára, ẹ sì ṣọ́ra, ní ti ìwúkàrà àwọn Farisí àti àwọn Sadusí.”

Mátíù 16

Mátíù 16:1-7