Mátíù 16:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù mú Jésù sí ẹ̀gbẹ́ kan, ó bẹ̀rẹ̀ sí í bá a wí pé, “Kí a má rí i Olúwa. Èyí kì yóò ṣẹlẹ̀ sí Ọ.”

Mátíù 16

Mátíù 16:19-25