Mátíù 16:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

È é ha ṣe tí kò fi yé yín pé èmi kò sọ̀rọ̀ nípa ti búrẹ́dì? Lẹ́ẹ̀kan sí i, mo wí fún yín, ẹ ṣọ́ra fún ìwúkàrà àwọn Farisí àti ti Sadusí.”

Mátíù 16

Mátíù 16:5-20