Mátíù 15:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì béèrè pé, “ìsù Búrẹ́dì mélòó ni ẹ̀yín ní?”Wọ́n sì dáhùn pé, “Àwa ní ìsù àkàrà méje pẹ̀lú àwọn ẹja wẹ́wẹ́ díẹ̀.”

Mátíù 15

Mátíù 15:33-37