Mátíù 15:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin náà wá, ó wólẹ̀ níwájú rẹ̀, ó bẹ̀bẹ̀ sí i pé, “Olúwa ṣàánú fún mi.”

Mátíù 15

Mátíù 15:22-27