Mátíù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá wọn lóhùn pé, “Gbogbo igi tí Baba mi ti ń bẹ ni ọ̀run kò bá gbìn ni á ó fà tu ti gbòǹgbò ti gbòǹgbò,

Mátíù 15

Mátíù 15:7-15