Mátíù 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù pe ọ̀pọ̀ ènìyàn wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, ó wí pé, “Ẹ tẹ́tí, ẹ sì jẹ́ kí nǹkan tí mo sọ yé yín.

Mátíù 15

Mátíù 15:8-19