Mátíù 14:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójú kan náà, Jésù na ọwọ́ rẹ̀, ó dì í mú, ó sì gbà á. Ó sì wí fún un pé, “Èé ṣe tí ìwọ fi ṣiyè méjì ìwọ onígbàgbọ́ kékeré?”

Mátíù 14

Mátíù 14:29-35