Mátíù 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá a lóhùn pé, “Ó dára, máa bọ̀ wá.”Nígbà náà ni Pétérù sọ̀ kalẹ̀ láti inú ọkọ̀. Ó ń rìn lórí omi lọ sí ìhà ọ̀dọ̀ Jésù.

Mátíù 14

Mátíù 14:22-36