Mátíù 14:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ní àkókò yìí ọkọ ojú-omi náà ti rin jìnnà sí etí bèbè òkun, tí ìjì omi ń tì í síwá sẹ́yìn, nítorí ìjì ṣe ọwọ́ òdì sí wọn.

Mátíù 14

Mátíù 14:15-30