Mátíù 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì gbé orí rẹ̀ jáde láti fi fún ọmọbìnrin náà nínú àwo pọ̀kọ́, òun sì gbà á, ó gbé etọ ìyá rẹ̀ lọ.

Mátíù 14

Mátíù 14:9-20