Mátíù 13:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù tún pa òwe mìíràn fún wọn: “Ìjọba ọ̀run dàbí èso hóró músítádì, èyí tí ọkùnrin kan mú tí ó gbìn sínú oko rẹ̀.

Mátíù 13

Mátíù 13:26-33