Mátíù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí ẹ̀yin kò ti kà á nínú òfin pé ní ọjọ́ ìsinmi, àwọn àlùfáà tí ó wà ní tẹ́ḿpílì ń ba ọjọ́ ìsinmi jẹ́ tí wọ́n sì wà láì jẹ̀bi.

Mátíù 12

Mátíù 12:1-6