Mátíù 12:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì fún ni èsì pé, “Ta ni ìyá mi? Ta ni àwọn arákùnrin mi?”

Mátíù 12

Mátíù 12:45-50