Mátíù 12:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni rere láti inú ìsúra rere ọkàn rẹ̀ ní i mú ohun rere jáde wá: àti ẹni búburu láti inú ìsúra búburú ni; mu ohun búburú jáde wá.

Mátíù 12

Mátíù 12:33-38