Mátíù 12:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“E ṣọ igi di rere, èso rẹ̀ a sì di rere tàbí kí ẹ sọ igi di búburú, èso rẹ a sì di búburú, nítorí nípa èso igi ni a ó fi mọ̀ ọ́n.

Mátíù 12

Mátíù 12:23-36