Mátíù 12:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, bi èmi bá ń lé àwọn ẹ̀mí ẹ̀ṣù jáde nípa Béélísébúbù, nípa ta ni àwọn ènìyàn yín fi ń lé wọn jáde? Nítorí náà ni wọn yóò ṣe má ṣe ìdájọ́ yín.

Mátíù 12

Mátíù 12:20-35