Mátíù 12:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun kì yóò jà. bẹ́ẹ̀ ni kì yóò kígbe;ẹnikẹ́ni kì yóò gbọ́ ohùn rẹ ní ìgboro.

Mátíù 12

Mátíù 12:13-26