Mátíù 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun gbogbo ni Baba mi ti fi sí ìkáwọ́ mi. Kò sí ẹni tí ó mọ ọmọ bí kò se Baba, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹnikẹ́ni tí ó mọ Baba, bí kò ṣe ọmọ, àti àwọn tí ọmọ yan láti fi ara hàn fún.

Mátíù 11

Mátíù 11:17-30