Mátíù 11:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìwọ Kápánámù, a ó ha gbé ọ ga sókè ọ̀run?, Rárá a ó rẹ̀ ọ́ sílẹ̀ sí ipò òkú. Nítorí, ìbá ṣe pé a ti ṣe iṣẹ́ ìyanu tí a ṣe nínú rẹ ní Sódómù, òun ìbá wà títí di òní.

Mátíù 11

Mátíù 11:19-30