Mátíù 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe mú wúrà tàbí fàdákà tàbí idẹ sínú àpò ìgbànú yín;

Mátíù 10

Mátíù 10:7-14