Mátíù 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù ran àwọn méjèèjìla yìí jáde, pẹ̀lú àṣẹ báyìí pé: “Ẹ má ṣe lọ sì àárín àwọn aláìkọlà tàbí wọ̀ èyíkèyìí ìlú àwọn ará Samáríà

Mátíù 10

Mátíù 10:1-15