Mátíù 10:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́wọ́ mi níwájú ènìyàn, òun náà ni èmi yóò jẹ́wọ́ rẹ̀ níwájú Baba mi ní ọ̀run.

Mátíù 10

Mátíù 10:24-33