Mátíù 10:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí mo bá wí fún yín ní òkùnkùn, òun ni kí ẹ sọ ní ìmọ́lẹ̀. Èyí tí mo sọ kẹ́lẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ sì etí yín ni kí ẹ kéde rẹ́ lórí òrùlé.

Mátíù 10

Mátíù 10:25-35