Mátíù 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tọ́ fún akẹ́kọ̀ọ́ láti dà bí olùkọ́ rẹ̀ àti fún ọmọ-ọ̀dọ̀ láti rí bí ọ̀gá rẹ̀. Nígbà tí wọ́n bá pe baálé ilé ní Béélísébúbù, mélòó mélòó ni ti àwọn ènìyàn ilé rẹ̀!

Mátíù 10

Mátíù 10:18-28