Mátíù 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ àwọn àpósítélì méjèèjìlá náà ni wọ̀nyí: ẹni àkọ́kọ́ ni Símónì ẹni ti a ń pè ni Pétérù àti arákùnrin rẹ̀ Ańdérù, Jákọ́bù ọmọ Sébédè àti arákùnrin rẹ̀ Jòhánù.

Mátíù 10

Mátíù 10:1-7