Mátíù 10:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mò ń rán yín lọ gẹ́gẹ́ bí àgùntàn sáàrin ìkookò. Nítorí náà, kí ẹ ní ìṣọ́ra bí ejò, kí ẹ sì ṣe onírẹ̀lẹ̀ bí àdàbà.

Mátíù 10

Mátíù 10:6-26