Mátíù 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ilé náa bá sì yẹ, kí àlàáfíà yín kí ó bà sórí rẹ̀; ṣùgbọ́n bí kò bá yẹ, kí àlàáfíà yín kí ó padà sọ́dọ̀ yín.

Mátíù 10

Mátíù 10:7-15