Mátíù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a ṣe bí Jésù nì yìí: Ní àkókò ti àdéhùn ìgbéyàwó ti parí láàrin Màríà ìyá rẹ̀ àti Jósẹ́fù, ṣùgbọ́n kí wọn tó pàdé, a rí i ó lóyún láti ọwọ́ Ẹ̀mí Mímọ́.

Mátíù 1

Mátíù 1:8-25