Málákì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì jókòó bí ẹni tí n yọ́, tí ó sì ń da fàdákà; yóò wẹ àwọn ọmọ Léfì mọ́, yóò sì tún wọn dà bí wúrà àti fàdákà, kí wọn bá a lè mú ọrẹ òdodo wá fún Olúwa,

Málákì 3

Málákì 3:1-6