Málákì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọn yóò sì jẹ́ tèmi,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí, “ni ọjọ́ náà, tí èmi ó dá; èmi yóò sì da wọ́n sí gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí máa ń dá ọmọ rẹ̀ tí yóò ń sìn ín sí.

Málákì 3

Málákì 3:13-18