Málákì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òfin òtítọ́ wà ni ẹnu rẹ̀, a kò sì rí irọ́ ni ètè rẹ̀: ó ba mi rìn ní àlàáfíà àti ni ídúró ṣinṣin, ó sì yí ọ̀pọ̀lọpọ̀ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀.

Málákì 2

Málákì 2:1-8