Málákì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí ti yín èmí yóò ba àwọn ọmọ yín wí èmi ó sì fi ìgbẹ́ rẹ́ yín lójú, àní àwọn ìgbẹ́ ọrẹ ọwọ́ yín wọ̀nyí, a ó sì kó yín lọ pẹ̀lú rẹ̀.

Málákì 2

Málákì 2:1-11