Málákì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Baba kan náà kí gbogbo wa ha ní? Ọlọ́run kan náà kọ́ ni ó dá wa bí? Nítorí kín ni àwa ha ṣe sọ májẹ̀mú àwọn baba wa di aláìmọ nípa híhùwà àrékérekè olúkulùkù sí arákùnrin rẹ̀?

Málákì 2

Málákì 2:4-17