Máàkù 9:46-50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

46. Níbi tí kòkòrò wọn kì í kú, tí iná nàá kì í sì í ku

47. Àti pé, bí ojú rẹ bá mú ọ kọsẹ̀, yọ ọ́ sọnù, ó sàn kí o wọ ìjọba Ọlọ́run pẹ̀lú ojú kan ju kí ó ní ojú méjì kí ó sì lọ sí inú iná ọ̀run àpáàdì.

48. Níbi ti“ ‘kòkòrò wọn kìí kú,,tí iná kì í sì í kú.’

49. Níbẹ̀ ni a ó ti fi iná dán ẹnìkọ̀ọ̀kan wò

50. “Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ agbára adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mu un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ni àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.”

Máàkù 9