Máàkù 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ronú èyí láàrin ara wọn wí pé, “Torí pé a kò mú búrédì lọ́wọ́ ni?”

Máàkù 8

Máàkù 8:10-21