Máàkù 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, lẹ́yìn èyí, Jésù wọ inú ọkọ̀ ojú-omi pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì gúnlẹ̀ sí agbègbè Dálímánútà.

Máàkù 8

Máàkù 8:2-12