Máàkù 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kan, bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ti péjọ, kò sí oúnjẹ fún wọn mọ́ láti jẹ. Jésù pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.

Máàkù 8

Máàkù 8:1-9