Máàkù 7:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì mú ọkùnrin náà kúrò láàrin ọ̀pọ̀ ènìyàn. Ó sì fi àwọn ìka rẹ̀ sí etí ọkùnrin náà, ó tu itọ sọ́wọ́. Ó sì fi kan ahọ́n rẹ̀.

Máàkù 7

Máàkù 7:29-37