Máàkù 7:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sọ fún obìnrin yìí pé, “Ní àkọ́kọ́, ó yẹ kí a fi oúnjẹ tẹ́ àwọn ọmọ lọ́rùn ná. Nítorí kò tọ́ kí a mú oúnjẹ àwọn ọmọ fún àwọn ajá.”

Máàkù 7

Máàkù 7:26-35