Máàkù 7:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láìpẹ́, obìnrin kan tí ọmọbìnrin rẹ̀ ní ẹ̀mí àìmọ́ tọ̀ ọ́ wá, ó ti gbọ́ nípa Jésù, ó wá, ó sì wólẹ̀ lẹ́ṣẹ̀ Jésù.

Máàkù 7

Máàkù 7:24-30