Máàkù 6:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù tún béèrè pé, “Ìṣù àkàrà mélòó ni ẹ̀yin ni lọ́wọ́? Ẹ lọ wò ó.”Wọ́n padà wá jíṣẹ́ pé, “Ìṣù àkàrà márùn ún àti ẹja méjì.”

Máàkù 6

Máàkù 6:31-47