Máàkù 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí pé, “Ẹ dúró sí ilé kan ní ìletò kan. Ẹ má ṣe ṣípò padà láti ilé dé ilé, nígbà tí ẹ bá wà ní ìlú náà.

Máàkù 6

Máàkù 6:1-16