Máàkù 5:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́sẹ̀kan-náà, ọmọbìnrin náà sì dìde. Ó sì ń rìn, ẹ̀rù sì ba wọn, ẹnú sì ya àwọn òbí rẹ̀ gidigidi.

Máàkù 5

Máàkù 5:36-43