Máàkù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jésù sì ti ń ti inú ọkọ̀ ojú omi jáde. Ọkùnrin kan tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́ jáde ti ibojì wá pàdé rẹ̀.

Máàkù 5

Máàkù 5:1-7